T. Gold – ADURA ODUN – Mp3

Download T. Gold – ADURA ODUN – Mp3

Nigerian gospel singer, recording Songstress, Oluwatoyin Ruth Ogunrinde.is from ipele owo in Ondo state. She is happily married with three children.

T. Gold releases a new single “ADURA ODUN,”
This is a soulful and introspective song that will surely bless your life.
Song Tittle: ADURA ODUN
Lead by chorus: Lodun Yi o, emi a rire gba..
Lodun Yi o emi arayo gba..
Eri mi a la agbaye ja Lodun Yi o, ma serere./2×
Lead vocal: Lodun Yi o emi a rire gba
Lodun Yi o emi a rayo gba
Eri mi a la agbaye ja Lodun Yi o ma se rere
Solo:1 Atiko nipa temi, pe imole ni mo je, odidandan kin tan faraiye ri. ninu odun ti mo wa Yi, ogo aiye mi abuyo, gbogbo okunkun a paree, Egan aiye mi a dogo, ileri OLUWA a se, ninu aiye mi, eri mi a la agbaye ja Lodun Yi o ma se rere
Chorus: Lodun Yi o……
Solo2: Iwo eti to n gbo mi (hen hen)
Mo fe koma Sa’min. (Amin)
Sa’min ko gbe’to ADURA mi (Amin)
Ninu odunti a wa Yi, (hen hen)
 OLUWA ni kin so fun o, (henhen)
po’hun yio pa Alo re mo,(Amin)
 ATI abo re mo. (Amin)
Oni buburu kankan, (henhen)
ko ni subu lu o ( Amin)
Oni gbogbo ohun to ba da’wole (henhen)
a yori si rere (Amin)
Ninu odun to wa yi, ( henhen)
visa ilu oyinbo re abosi (Amin)
O ma gba letter ayo(Amin)
O ma rire gba mu (Amin)
Wa Rona gbe gba (Amin)
Oni rogun aisan (Amin)
Osi oni whole to o wa (Amin)
Omo oniku mo o loju (Amin)
O ni ri iku oko (Amin)
Aya oni ku mo o lowo (Amin)
Oro re a dayo (Amin)
Eri re Al agbaye ja Lodun Yi o wa se rere.
Social Media Below
Whatsapp: 07056892734
Instagrams: Oluwatoyin1gold
Facebook:  Oluwatoyin T. Gold
Download And Enjoy Below

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *